Pólàndì

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Republic of Poland
Rzeczpospolita Polska
Àsìá
MottoNone1
Orin-ìyìn orílẹ̀-èdèMazurek Dąbrowskiego
(Dąbrowski's Mazurka)
Ibùdó ilẹ̀  Pólàndì  (dark green)– on the European continent  (light green & dark grey)– in the European Union  (light green)  —  [Legend]
Ibùdó ilẹ̀  Pólàndì  (dark green)

– on the European continent  (light green & dark grey)
– in the European Union  (light green)  —  [Legend]

Olúìlú
(àti ìlú títóbijùlọ)
Warsaw
52°13′N 21°02′E / 52.217°N 21.033°E / 52.217; 21.033
Èdè oníbiṣẹ́ Polish2
Orúkọ aráàlú Ará Pólàndì
Ìjọba Parliamentary republic
 -  Acting President Bronisław Komorowski
 -  Prime Minister Donald Tusk
Formation
 -  Christianisation4 966 
 -  First Republic July 1, 1569 
 -  Second Republic November 11, 1918 
 -  People's Republic December 31, 1944 
 -  Third Republic January 30, 1990 
Ọmọ ẹgbẹ́ EU 1 May 2004
Ààlà
 -  Àpapọ̀ iye ààlà 312,679 km2 (69th3)
120,726 sq mi 
 -  Omi (%) 3.07
Olùgbé
 -  Ìdíye Jan 2010 38,163,895[1] (34th)
 -  December 2007 census 38,116,000[2] (34th)
 -  Ìṣúpọ̀ olùgbé 122/km2 (83rd)
319.9/sq mi
GIO (PPP) ìdíye 2008
 -  Iye lápapọ̀ $668.551 billion[3] (21st)
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $17,536[3] (50th)
GIO (onípípè) Ìdíye 2008
 -  Àpapọ̀ iye $527.866 billion[3] (18th)
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $13,846[3] (50th)
Gini (2002) 34.5 
HDI (2007) 0.880[4] (high) (41st)
Owóníná Złoty (PLN)
Àkókò ilẹ̀àmùrè CET (UTC+1)
 -  Summer (DST) CEST (UTC+2)
Ìwakọ̀ ní ọwọ́ right
Àmìọ̀rọ̀ Internet .pl
Àmìọ̀rọ̀o tẹlifóònù 48
1 See, however, Unofficial mottos of Poland.
2 Although not official languages, Belarusian, Kashubian, Lithuanian and German are used in 20 communal offices.
3 The area of Poland according to the administrative division, as given by the Central Statistical Office, is 312,679 km2 (120,726 sq mi) of which 311,888 km2 (120,421 sq mi) is land area and 791 km2 (305 sq mi) is internal water surface area.[2]
4 The adoption of Christianity in Poland is seen by many Poles, regardless of their religious affiliation or lack thereof, as one of the most significant national historical events; the new religion was used to unify the tribes in the region.

Pólàndì en-us-Poland.ogg /ˈpoʊlənd/ (Pólándì: Polska), fun ibise gege bi orile-ede Olominira ile Poland (Rzeczpospolita Polska), je orile-ede ni Aarin Europe [5][6] to ni bode mo Jẹ́mánì si iwoorun; Tsek Olominira ati Slofakia si guusu; Ukraine, Belarus ati Lituéníà si ilaorun; ati Okun Baltiki pelu Kaliningrad Oblast, to wa ni Rosia, ni ariwa. Gbogbo ifesi agbegbe ile Poland je 312,679 square kilometres (120,726 sq mi),[2] to so di orile-ede 69th titobijulo ni aye ati ikesan titobijulo ni Europe. Poland ni iye awon eniyan to ju 38 legbegberun lo,[2] eyi so di orile-ede 34th toleniyanjulo ni aye[7] ati ikan ninu awon toleniyanjulo ni Isokan Europe.

Idasile orile-ede Poland bere pelu Esin Kristi latowo Mieszko I olori ibe, ni odun 966, nigbati orile-ede yi gba gbogbo aye ti Poland gba loni. Ile-Oba Poland je didasile ni 1025, ni odun 1569 o bere long ajosepo pipe pelu Grand Duchy of Lithuania nipa titowobo Isokan ilu Lublin, to sedasile Ajoni Polandi ati Lithuania.

Ajoni yi wo ni 1795, be sini Poland je pipin larin Ile-Oba Prussia, Ile-Oluoba Rosia, ati Austria. Poland pada gba ilominira ni Igba Oselu Keji Poland ni 1918, leyin Ogun Agbaye Akoko, sugbon o je didurolori latowo Jẹ́mánì Nazi ati Isokan Sofieti nigba Ogun Agbaye Keji. Poland pofo emin awon eniyan toju egbegberun 6 lo ninu Ogun Agbaye Keji, o bere lekansi gege bi orile-ede Olominira awon Ara ile Poland larin Blok Ilaorun labe olori Sofieti.

Nigba awon Ijidide odun 1989, ijoba komunisti wolule leyin re Poland di "Oselu Keta Poland" pelu ofin ibagbepo. Poland je orile-ede onisokan, to je idipo awon ipinle merindilogun (Pólándì: województwo). Poland je ikan ninu Isokan Europe, NATO, Agbajo awo Orile-ede, Agbajo Idunadura Agbaye, ati Agbajo fun Ifowosowopo Okowo ati Idagbasoke (OECD).


[àtúnṣe] Itokasi

Àwọn irinṣẹ́ àdáni
Àwọn orúkọàyè
Àwọn oriṣiríṣi
Àwọn ìfihàn
Àwọn ìgbéṣe
Atọ́ka
Ìkópa
Àpótí irinṣẹ
Àwọn èdè míràn