Austríà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Orílẹ̀òmìnira ilẹ̀ Austríà
Republic of Austria
Republik Österreich
Àsìá Àmì ọ̀pá àṣẹ
Orin-ìyìn orílẹ̀-èdèLand der Berge, Land am Strome  (German)
Land of Mountains, Land by the River


Ibùdó ilẹ̀  Austríà  (dark green)– on the European continent  (green & dark grey)– in the European Union  (green)  —  [Legend]
Ibùdó ilẹ̀  Austríà  (dark green)

– on the European continent  (green & dark grey)
– in the European Union  (green)  —  [Legend]

Olúìlú
(àti ìlú títóbijùlọ)
Vienna
48°12′N 16°21′E / 48.2°N 16.35°E / 48.2; 16.35
Èdè oníbiṣẹ́ German
Àwọn èdè dídámọ̀ níbẹ̀ Slovene, Croatian, and Hungarian
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn (2001) 91.1% Austrians,
8.9% foreigners -
4% former Yugoslavs,
1.6% Turks,
2.4% others and unspecified[1]
Orúkọ aráàlú Ará Austríà
Ìjọba Federal Parliamentary republic
 -  Ààrẹ Heinz Fischer
 -  Kánsélọ̀ Werner Faymann (SPÖ)
 -  Ààrẹ Ìgbìmọ̀ Ọlọ́mọorílẹ̀-èdè Barbara Prammer (SPÖ)
Independence
 -  Austrian State Treaty in force 27 July 1955 (Duchy: 1156, Austrian Empire: 1804, First Austrian Republic: 1918–1938, Second Republic since 1945) 
Ọmọ ẹgbẹ́ EU 1 January 1995
Ààlà
 -  Àpapọ̀ iye ààlà 83,855 km2 (115th)
32,377 sq mi 
 -  Omi (%) 1.7
Alábùgbé
 -  Ìdíye 2011 8,404,252[2] (92nd)
 -  2001 census 8,032,926 
 -  Ìṣúpọ̀ olùgbé 99/km2 (99th)
257/sq mi
GIO (PPP) ìdíye 2010
 -  Iye lápapọ̀ $332.005 billion[3] 
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $39,634[3] 
GIO (onípípè) Ìdíye 2010
 -  Àpapọ̀ iye $376.841 billion[3] 
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $44,986[3] 
Gini (2007) 26[4] (low
HDI (2010) 0.851[5] (very high) (25th)
Owóníná Euro () ² (EUR)
Àkókò ilẹ̀àmùrè CET (UTC+01)
 -  Summer (DST) CEST (UTC+02)
Ìwakọ̀ ní ọwọ́ ọ̀tún
Àmìọ̀rọ̀ Internet .at ³
Àmìọ̀rọ̀o tẹlifóònù 43
1 Slovene, Croatian, Hungarian are officially recognised regional languages and Austrian Sign Language is a protected minority language throughout the country.
2 Euro since 1 Jan 1999 virtual, since 1 Jan 2002 real currency; before: Austrian Schilling.
3 The .eu domain is also used, as it is shared with other European Union member states.

Austríà (Gbígbọ́i /ˈɒustriə/ tabi /ˈɔːstriə/; Jẹ́mánì: Österreich [ˈøːstəˌʁaɪç]  ( listen)), lonibise bi Orileominira ile Austria (German: Republik Österreich), je orile-ede atimo ile to ni awon eniyan bi egbegberun 8.4[2] to wa ni Aringbongan Europe. O ni bode mo Orileominira Tseki ati Jemani ni ariawa, Slofakia ati Hungari ni ilaorun, Slofenia ati Italia ni gusu, ati Switsalandi ati Likstenstein ni iwoorun. Gbogbo agbegbe ile Austria je 83,855 ìlọ́poméjì kilometres (32,377 sq mi) be sini ojuojo ibe je onitutu ati alpini. Ori ile Austria je oloke gan nitori pe awon Alpi po nibe; 32% ibe nikan ni won wa ni abe 500 metres (1,640 ft), be sin oke re togajulo je 3,798 metres (12,461 feet).[6] Opo awon iyeolubugbe unso ede Jemani,[7] to tun je ede onibise orile-ede ohun.[8] Awon ede ibile onibise miran tun ni ede Kroatia, Hungari ati Slofenia.[6]

Austria loni ni ibere re lati igba iran-oba Habsburg gegebi ara Obaluaye Romu Mimoy ti Orile-ede awon Ara Jemani; Austria di ikan ninu awon alagbara ninla ile Europe. Ni 1867, Ileobaluaye Austria je sisodi Austria-Hungary.

Obaluaye awon iran Habsburg (Austro-Hungarian) daru ni 1918 leyin opin Ogun Agbaye 1k, nigba Austria lo Austria Ara Jemani bi oruko („Deutschösterreich”, todi „Österreich”) lati ba se isokan po mo Jemani sugbon Adehun Saint Germain lodi si eyi. Igba Oselu Austria Akoko je didasile ni 1919. Ni igba Anschluss 1938, Austria je bibolori latowo Jemani awon Nasi.[9] Eyi je be titi di opin Ogun Agbaye 2k ni 1945, leyin ti Jemani awon Nasi je bibori ogun latowo awon Ore eyi lo da oselu pada si Austria. Ni 1955, Adehun Orile-ede Ara Austria satun-dasile Austria gegebi orile-ede alaselorile, lati fopin si ibolori. Ni odun yi kanna, Ileasofin Austria da Ifilole Aisojusaju to filole pe Igba Oselu Austria Keji yio di alaisojusaju titi lailai.

Loni, Austria je oseluarailu asoju parliamentary|onileasofin to ni awon ipinle mesan.[6][10] Oluilu ati ilu re totobijulo, pelu iyeolubugbe to ju egbegberun 1.6, ni Vienna.[6][11] Austria je ikan ninu awon orile-ede to lolajulo lagbaye, pelu IO oloruko ti enikookan to je $43,723 (idiye 2010). Orile-ede ohun ti sedagbasoke ona igbe giga, be sini ni 2010 o je onipo 25k lagbaye fun Atoka Idagbasoke Omoniyan re. Austria ti je omo egbe Awon Orile-ede Asokan lati 1955,[12] o sora po mo Isokan Ara Europe ni 1995,[6] be sini o je ikan larin awon ti won da OECD sile.[13] Austria tun fowobowe Ifenuko Schengen ni 1995,[14] o si gba owonina Europe, euro, ni 1999.





Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. World Factbook (3 August 2010). "Austria". CIA. https://www.cia.gov/library/publications/the-world-factbook/geos/au.html. Retrieved 14 August 2010. 
  2. 2.0 2.1 "Bevölkerung zu Jahresbeginn seit 1981". Statistik Austria. 19 May 2011. http://www.statistik.at/web_de/static/ergebnisse_im_ueberblick_bevoelkerung_zu_jahresbeginn_022497.pdf. Retrieved 19 May 2011. 
  3. Cite error: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named imf2
  4. "Distribution of family income – Gini index". The World Factbook. CIA. https://www.cia.gov/library/publications/the-world-factbook/fields/2172.html. Retrieved 1 September 2009. 
  5. "Human Development Report 2010". United Nations. 2010. http://hdr.undp.org/en/media/HDR_2010_EN_Table1.pdf. Retrieved 5 November 2010. 
  6. 6.0 6.1 6.2 6.3 6.4 "The World Factbook – Austria". Central Intelligence Agency. 14 May 2009. https://www.cia.gov/library/publications/the-world-factbook/geos/au.html. Retrieved 31 May 2009. 
  7. "Die Bevölkerung nach Umgangssprache, Staatsangehörigkeit und Geburtsland". Statistik Austria. http://www.statistik.at/web_de/static/bevoelkerung_2001_nach_umgangssprache_staatsangehoerigkeit_und_geburtsland_022896.pdf. Retrieved 17 November 2010. 
  8. "Austria". Encyclopædia Britannica. Encyclopædia Britannica Online. 31 May 2009. http://www.britannica.com/EBchecked/topic/44183/Austria. Retrieved 31 May 2009. 
  9. "Anschluss". Encyclopædia Britannica. Encyclopædia Britannica Online. 24 September 2009. http://www.britannica.com/EBchecked/topic/26730/. Retrieved 31 May 2009. 
  10. Lonnie Johnson 17
  11. "Probezählung 2006 – Bevölkerungszahl 31.10.2006" (in German) (PDF). Statistik Austria. 31 October 2006. http://www.statistik.at/blickgem/pz1/g90001.pdf. Retrieved 27 May 2009. 
  12. Jelavich 267
  13. "Austria About". OECD. http://www.oecd.org/about/0,3347,en_33873108_33873245_1_1_1_1_1,00.html. Retrieved 20 May 2009. 
  14. "Austria Joins Schengen". Migration News. May 1995. http://migration.ucdavis.edu/mn/more.php?id=643_0_4_0. Retrieved 30 May 2009.