Bangladẹ́shì

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
People's Republic of Bangladesh
গণপ্রজাতন্ত্রী বাংলাদেশ
Gônoprojatontri Bangladesh
Àsìá Àmì ọ̀pá àṣẹ
Orin-ìyìn orílẹ̀-èdèAmar Shonar Bangla
My Golden Bengal

Olúìlú
(àti ìlú títóbijùlọ)
Dhaka
23°42′N 90°21′E / 23.7°N 90.35°E / 23.7; 90.35
Èdè oníbiṣẹ́ Bangla
Orúkọ aráàlú Ará Bangladẹ́shì
Ìjọba Parliamentary republic[1]
 -  President Zillur Rahman
 -  Prime Minister Sheikh Hasina Wazed
 -  Speaker Ad.Abdul Hamid
Independence from Pakistan 
 -  Declared March 26, 1971 
Ààlà
 -  Àpapọ̀ iye ààlà 147,570 km2 (94th)
55,599 sq mi 
 -  Omi (%) 7.0
Alábùgbé
 -  Ìdíye 2009 162,221,000[2] (7th)
 -  Ìṣúpọ̀ olùgbé 1,099.3/km2 (5th)
2,917.6/sq mi
GIO (PPP) ìdíye 2009
 -  Iye lápapọ̀ $226.205 billion[3] (48th)
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $1,398[3] (153rd)
GIO (onípípè) Ìdíye 2008
 -  Àpapọ̀ iye $84.196 billion[3] (58th)
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $690[4] (147th)
Gini (2000) 33.4 (medium
HDI (2007) 0.543[5] (medium) (146th)
Owóníná Taka (BDT)
Àkókò ilẹ̀àmùrè BST (UTC+6)
Ìwakọ̀ ní ọwọ́ left
Àmìọ̀rọ̀ Internet .bd
Àmìọ̀rọ̀o tẹlifóònù 880
1 Adjusted population, p.4,

En-Bangladesh.ogg Bangladesh (Bengali: বাংলাদেশ, pronounced [ˈbaŋlad̪eʃ]; Bangladesh), fun ibise gege bi orile-ede Olominira Araalu ile Bangladesh (Bengali: গণপ্রজাতন্ত্রী বাংলাদেশ Gônoprojatontri Bangladesh) je orile-ede kan ni Guusu Asia. O ni bode mo India ni gbogbo awon egbe re ayafi fun bode kekere mo Burma (Myanmar) ni guusuilaorun ati mo Ebado Bengal ni guusu. Lapapo mo ipinle West Bengal ni India, o je agbegbe eya-ede Bengal. Oruko Bangladesh tumosi "Orile-ede ile Bengal" ni ede ibise Bengal.

Awon bode Bangladesh lowolowo loni je didasile pelu ipinya Bengal ati India ni 1947, nigbati agbegbe na di egbe apailaorun orile-ede tuntun Pakistan. Sugbon, o pinsoto lati egbe apaiworun pelu 1,600 km (994 mi) ile India. Nitori idawaloto oloselu ati ede ati aisi okowo to fa isodi awon araalu si Iwoorun Pakistan, to fa ogun fun ilominira ni 1971 ati idasile orile-ede Bangladesh. Leyin ilominira orile-ede tuntun yi koju iyan, ajalu eda ati aini togbale, ati wahala oselu ati igbajoba ologun. Ipadade oseluaraalu ni 1991 mu itoro ati idagbasoke okowo wa.

Bangladesh ni orile-ede keje to lopo eniyan julo ati ikan ninu awon orile-ede to lopo eniyan kikijulo laye pelu osuwon aini giga. Sibesibe, GDP ti enikookan ti di emeji lati 1975, be sini osuwon aini ti re bi 20% lati ibere awon odun 1990. Bangladesh je ikan ninu awon orile-ede ti a npe ni okowo "Next Eleven". Dhaka, oluilu re, ati awon gbongan igboro ilu miran kopa ninu idagbasoke yi.[6]

Fun jeografi, orile-ede yi gba ile olora Delta Ganges-Brahmaputra be sini oun ni omoyale lododun ojo monsoon ati iji birikiti. Bangladesh ni ile yepe eti-odo to gunjulo laye ni ti Cox's Bazaar. Oselu re ni oseluaralu ile-asofin. Bangladesh je ikan ninu Ajoni awon Orile-ede, OIC, SAARC, BIMSTEC, ati D-8. Gege bi Banki Agbaye se sakiyesi ninu Oro nisoki Orile-ede re ni July 2005, Bangladesh ti ni ilosiwa gidi ni idagbasoke eniyan ni apa imookomooka, idogba ako/abo ni ile-eko ati iresile ipoju awon eniyan.[7] However, Bangladesh si nkoju awon isoro nla, ajakale iwaibaje awon oloselu ati osise ijoba, economic competition relative to the world, serious overpopulation, widespread poverty, and an increasing danger of hydrologic shocks brought on by ecological vulnerability to climate change.

National symbols of Bangla-Desh (Official)
State animal Panthera tigris.jpg
State bird Oriental Magpie Robin (Copsychus saularis)- Male calling in the rain at Kolkata I IMG 3746.jpg
State tree Mango blossoms.jpg
State flower National flower of Bangladesh.jpg
State aquatic marine mammal PlatanistaHardwicke.jpg
State reptile Gavial-du-gange.jpg
State fruit (Artocarpus heterophyllus) Jack fruits on Simhachalam Hills 01.jpg
State fish Ilish.JPG
State mosque Baitul Mukarram (Arabic, بيت المكرّم; Bengali, বায়তুল মুকাররম; The Holy House).jpg
State temple Hindu Temple in Dhaka.jpg
State river Boat on Jamuna River.jpg
State mountain Keokradong.jpg

Itan[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Somapura Mahavihara in Paharpur, Bangladesh is the greatest Buddhist Vihara in the Indian Subcontinent, built by Dharmapala of Bengal.
Sixty Dome Mosque in Mosque city of Bagerhat was built in the 15th century and is the largest historical mosque in Bangladesh, as well as a World Heritage site.
The Shaheed Minar, which commemorates the Bengali Language Movement, is a well known landmark in Bangladesh.
Fáìlì:P015.gif
Sheikh Mujibur Rahman (3rd person from right), founder of Bangladesh and Maulana Bhashani (4th person from right) in 1953.

Awon iseku asaolaju ni agbegbe Bengal loseyin de egberun merin odun,[8] nigbati ibe je titedo lowo awon Dravidian, Tibeto-Burman, ati awon Austro-Asiatic. Orisun oro Bangla" tabi "Bengal" ko je mimo, botilejepe won nigbagbo pe o wa lati Bang, eya to n sede Dravidian to budo si agbegbe yi larin odun 1000 kJ.[9]










Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Constitution of Bangladesh, Part V, Chapter 1, Article 66.
  2. Department of Economic and Social Affairs Population Division (2009) (.PDF). World Population Prospects, Table A.1. 2008 revision. United Nations. http://www.un.org/esa/population/publications/wpp2008/wpp2008_text_tables.pdf. Retrieved 2009-03-12. 
  3. 3.0 3.1 3.2 "Bangladesh". International Monetary Fund. http://www.imf.org/external/pubs/ft/weo/2009/02/weodata/weorept.aspx?sy=2006&ey=2009&scsm=1&ssd=1&sort=country&ds=.&br=1&c=513&s=NGDPD%2CNGDPDPC%2CPPPGDP%2CPPPPC%2CLP&grp=0&a=&pr.x=35&pr.y=9. Retrieved 2009-10-01. 
  4. Bangladesh Bank, Annual Report 2008-09.
  5. "Human Development Report 2009. Human development index trends: Table G". The United Nations. http://hdr.undp.org/en/media/HDR_2009_EN_Complete.pdf. Retrieved 2009-10-05. 
  6. Sandeep Mahajan, "Bangladesh: Strategy for Sustained Growth", Poverty Reduction and Economic Management Network, World Bank (July 26, 2007)
  7. Bangladesh – Country Brief, World Bank, July 2005
  8. Bharadwaj, G (2003). "The Ancient Period". In Majumdar, RC. History of Bengal. B.R. Publishing Corp. 
  9. James Heitzman and Robert L. Worden, ed (1989). "Early History, 1000 B.C.-A.D. 1202". Bangladesh: A country study. Library of Congress. ISBN 8290584083. OCLC 15653912. http://memory.loc.gov/frd/cs/bdtoc.html. 

Àdàkọ:Link FA