Mọ́rísì

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí

Àwọn Akóìjánupọ̀: 20°12′S 57°30′E / 20.2°S 57.5°E / -20.2; 57.5

Olómìnira ilẹ̀ Mọ́rísì
Republic of Mauritius
Repiblik Moris
République de Maurice
Àsìá Àmì ọ̀pá àṣẹ
Motto"Stella Clavisque Maris Indici"  (Latin)
"Star and Key of the Indian Ocean"
Orin-ìyìn orílẹ̀-èdèMotherland
Olúìlú Port Louis
20°10′S 57°31′E / 20.167°S 57.517°E / -20.167; 57.517
Èdè oníbiṣẹ́ English[1][2]
Vernacular Mauritian Creole, French, English
Orúkọ aráàlú Ará Mọ́rísì
Ìjọba Parliamentary republic
 -  President Anerood Jugnauth
 -  Prime Minister Navin Ramgoolam
Independence from the United Kingdom 
 -  Date 12 March 1968 
 -  Republic 12 March 1992 
Ààlà
 -  Àpapọ̀ iye ààlà 2,040 km2 (179th)
787 sq mi 
 -  Omi (%) 0.05
Alábùgbé
 -  Ìdíye 2009 1,288,000[3] (151st)
 -  2000 census 1,179,137 
 -  Ìṣúpọ̀ olùgbé 631.4/km2 (18th)
1,636.5/sq mi
GIO (PPP) ìdíye 2008
 -  Iye lápapọ̀ $15.273 billion[4] 
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $12,011[4] 
GIO (onípípè) Ìdíye 2008
 -  Àpapọ̀ iye $8.738 billion[4] 
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $6,871[4] 
HDI (2004) 0.802 (high) (65th)
Owóníná Mauritian rupee
Àkókò ilẹ̀àmùrè MUT (UTC+4)
 -  Summer (DST)  (UTC+5 (2008 only)[5][6])
Ìwakọ̀ ní ọwọ́ left
Àmìọ̀rọ̀ Internet .mu
Àmìọ̀rọ̀o tẹlifóònù 230

Mọ́rísì (pípè /məˈrɪʃəs/; Faranse: L’île Maurice pípè: [lil mɔˈʁis], Mauritian Creole: Moris; Geesi: Mauritius), fun ibise gege bi orile-ede Olominira ile Morisi (Faranse: République de Maurice) je orile-ede erekusu lebado Afrika ni guusuiwoorun Okun Indiain, bi 900 kilometres (560 mi) ilaorunt orile-ede Madagascar. Lapapo mo erekusu Morisi, orile-ede yi na tun ni awon erekusu Cargados Carajos, Rodrigues ati Agalega Islands. Morisi je ikan ninu awon Erekusu Mascarene, pelu erekusu Fransi Réunion ni 200 km (120 mi) si guusuiwoorun ati erekusu Rodrigues ni 570 km (350 mi) si ariwailaorun.

Titi de orundun 17, awon ara Holandi ni won joba lori ibe leyin awon ara Fransi gba leyin ti awon ara Holandi ti fi sile. Awon ara Britani gba ibe nigba awon Ogun Napoleoni, ile Morisi si gba ominira lowo Britani ni odun 1968. Orile-ede Morisi je orile-ede olominira onileasofin beni o si je omo egbe Agbajo Idagbasoke Apaguusu Afrika, Common Market for Eastern and Southern Africa, Isokan Afrika ati Ajoni awon Orile-ede.

Awon ede pataki ibe ni Kreoli Morisi, Faranse ati Geesi. Geesi nikan ni ede ibise sugbon lingua franca je Creole be sini awon iwe-iroyin ati eto telifisan tun le je ni ede Farans.[7] Ni ti eya eniyan, ogunlogo awon ara ibe je ara India be sini opolopo awon omo Afrika lo tun wa nibe ati bakana bi awon omo Europe ati omo Saina die. Ohun nikan ni orile-ede Afrika nibi ti esin totobijulo ibe je esin Hindu botilejepe awon elesin Kristi ati musulumi na wa nibe sugbon ni iye kenkele.

Ìtàn[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

A postcard c.1900-1910 showing the Port Louis theatre.

Morisi ko ni awon eniyan rara ki o to di pe awon oluwakiri ara Europe te ibe do ni awon odun 1600s.[8] Awon Arabu ati awako oju-omi ara Austronesia mo erekusu yi lati orundun 10.[9] Awon awako oju-omi ara Portugal koko be ibe wo ni 1507 won si ko ibujoko sibe laigbe ibe. Oko oju-omi marun ile Hollandi ti Egbe-oko Keji je fifanka kuro lona won nigba iji nla nigbati won nlo si Spice Islands won si bale si Morisi ni 1598, nitorie won fun ibe ni oruko yi fun eye Omoba Maurice ile Nassau, Alagbato ile Netherlands.[10][11]



Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Article 49 of The Constitution". National Assembly of Mauritius. http://www.gov.mu/portal/site/AssemblySite/menuitem.ee3d58b2c32c60451251701065c521ca/?content_id=4cb54555fc808010VgnVCM100000ca6a12acRCRD#assembly. Retrieved 2009-02-08. 
  2. "Republic of Mauritius, Government Portal (Mauritius)". http://www.gov.mu/portal/site/abtmtius/menuitem.42f3149f267522984d57241079b521ca. 
  3. Department of Economic and Social Affairs Population Division (2009) (.PDF). World Population Prospects, Table A.1. 2008 revision. United Nations. http://www.un.org/esa/population/publications/wpp2008/wpp2008_text_tables.pdf. Retrieved 2009-03-12. 
  4. 4.0 4.1 4.2 4.3 "Mauritius". International Monetary Fund. http://www.imf.org/external/pubs/ft/weo/2009/02/weodata/weorept.aspx?sy=2006&ey=2009&scsm=1&ssd=1&sort=country&ds=.&br=1&c=684&s=NGDPD%2CNGDPDPC%2CPPPGDP%2CPPPPC%2CLP&grp=0&a=&pr.x=47&pr.y=3. Retrieved 2009-10-01. 
  5. Mauritius turns the clock forward in October 2008
  6. Mauritius will not repeat daylight saving time
  7. Coexistence International at Brandeis University
  8. Mauritius, Réunion & Seychelles. Lonely Planet. 2007. p. 37. ISBN 1741047277, 9781741047271. http://books.google.co.uk/books?id=x6dxoKuhDIIC&pg=PA37&dq=mauritius+first+inhabitants&hl=fr&cd=4#v=onepage&q=mauritius%20first%20inhabitants&f=false. Retrieved 2010-01-28. 
  9. "CIA - The World Factbook -- Mauritius". CIA. https://www.cia.gov/library/publications/the-world-factbook/geos/mp.html#Intro. Retrieved 2007-05-04. 
  10. Mutch, T. D. (1942). The First Discovery of Australia. Sydney: Project Gutenberg of Australia. pp. 55. http://gutenberg.net.au/ebooks06/0600631h.html. , p.13.
  11. The Hudson River in North America was first named "Mauritius River" for the same Stadtholder.