Àgbájọ àwọn Orílẹ̀-èdè Aṣòkan

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Map of UN member statesNote that this map does not represent the view of its members or the UN concerning the legal status of any country.[1]
Map of UN member states
Note that this map does not represent the view of its members or the UN concerning the legal status of any country.[1]
Headquarters International territory in Manhattan, New York City
Official languages Arabic, Chinese, English, French, Russian, Spanish
Ọmọ ẹgbẹ́ 192 member states
Àwọn olórí
 -  Secretary-General Ban Ki-moon
Ìdásílẹ̀
 -  United Nations Charter 26 June 1945 
 -  Ratification of Charter 24 October 1945 
Ibiatakùn
http://www.un.org/

Àgbájọ àwọn Orílẹ̀-èdè Aṣòkan tabi Àwọn Orílẹ̀-èdè Aṣòkan ni soki (AOA; Geesi: UNO tàbí UN) jẹ́ àgbájọ káríayé ti eto re je lati fa ifowosowopo ninu ofin kakiriaye, abo kakiriaye, idagbasoke eto inawole, ilosiwaju awujo, eto omoniyan ati imudaju alafia lagaye. OA je didasile ni odun 1945 leyin Ogun Agbaye Keji lati sedipo Apejo awon Orile-ede, lati jawo awon ogun larin awon orile-ede, ki o si pese aye fun ijiroro larin won. O ni opolopo eka akojoegbe kekeke lati le se awon ise wonyi.



Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "The World Today" (PDF). http://www.un.org/Depts/Cartographic/map/profile/world00.pdf. Retrieved 2009-06-18. "The designations employed and the presentation of material on this map do not imply the expression of any opinion whatsoever on the part of the Secretariat of the United Nations concerning the legal status of any country" 

Àdàkọ:Link FA

Àdàkọ:Link FA Àdàkọ:Link FA Àdàkọ:Link FA Àdàkọ:Link FA