Pọ́rtúgàl

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Orílẹ̀òmìnira Pọ́rtúgàl
Portuguese Republic
República Portuguesa
Àsìá Àmì ọ̀pá àṣẹ
Orin-ìyìn orílẹ̀-èdè"A Portuguesa"
"The Portuguese Hymn"
Ibùdó ilẹ̀  Pọ́rtúgàl  (dark green)

– on the European continent  (green & dark grey)
– in the European Union  (green)  —  [Legend]

Olúìlú
(àti ìlú títóbijùlọ)
Lisbon
38°46′N 9°9′W / 38.767°N 9.15°W / 38.767; -9.15
Èdè oníbiṣẹ́ Portuguese
Àwọn èdè dídámọ̀ níbẹ̀ Mirandese1
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn (2007) 96.87% Portuguese and 3.13% legal immigrants (Cape Verdeans, Brazilians, Ukrainians, Angolans, etc.)[1]
Orúkọ aráàlú Ará Pọ́rtúgàl
Ìjọba Orílẹ̀òmìnira oníléaṣòfin
 -  Ààrẹ Aníbal Cavaco Silva
 -  Alákóso Àgbà Pedro Passos Coelho
 -  Ààrẹ Iléaṣòfin Assunção Esteves
Formation Conventional date for Independence is 1139 
 -  Founding 868 
 -  Re-founding 1095 
 -  De facto sovereignty 24 June 1128 
 -  Kingdom 25 July 1139 
 -  Recognized 5 October 1143 
 -  Papal Recognition 23 May 1179 
 -  Restoration of independence 1 December 1640 
 -  Restoration of independence recognized 13 February 1668 
 -  Republic 5 October 1910 
Ààlà
 -  Àpapọ̀ iye ààlà 92,090 km2 (110th)
35,645 sq mi 
 -  Omi (%) 0.5
Alábùgbé
 -  Ìdíye 2011 10,647,763[2] (77th)
 -  2011 census 10,555,853[3] 
 -  Ìṣúpọ̀ olùgbé 115/km2 (96th)
298/sq mi
GIO (PPP) ìdíye 2010
 -  Iye lápapọ̀ $247.037 billion[4] 
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $23,222[4] 
GIO (onípípè) Ìdíye 2010
 -  Àpapọ̀ iye $229.336 billion[4] 
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $21,558[4] 
Gini (1997) 38.5[5] 
HDI (2010) 0.795[6] (very high) (40th)
Owóníná Euro ()2 (EUR)
Àkókò ilẹ̀àmùrè WET3 (UTC0)
 -  Summer (DST) WEST (UTC+1)
Ìdá ọjọ́ọdún dd-mm-yyyy, yyyy-mm-dd, yyyy/mm/dd
Ìwakọ̀ ní ọwọ́ right
Àmìọ̀rọ̀ Internet .pt4
Àmìọ̀rọ̀o tẹlifóònù 351
1 Mirandese, spoken in some villages of the municipality of Miranda do Douro, was officially recognized in 1999 (Lei n.° 7/99 de 29 de Janeiro), since then awarding an official right-of-use Mirandese to the linguistic minority it is concerned.[7] The Portuguese Sign Language is also recognized.
2 Before 1999: Portuguese escudo.

Pọ́rtúgàl (Gbígbọ́i /ˈpɔrʉɡəl/ Pọrtugí: Portugal), lonibise bi Orileominira Portugal (Pọrtugí: República Portuguesa[8]), je orile-ede to budo si apaguusuiwoorun Europe lori Penisula Iberia. Portugal ni orile-ede to sunmo apa iwoorun julo ni Europe, be sini o ni bode mo Okun Atlantiki ni iwoorun ati ni guusu, bode mo Spain ni ariwa ati ilaorun. Awon isujo erekusu inu Atlantiki, eyun Azores ati Madeira je ara Portugal. Orile-ede yi gba oruko re lati ibi oruko ilu re totobijulo keji, Porto, ti oruko Latini re je Portus Cale.

Ori ile to wa ninu bode Orileominira Portugal loni ti je titedo leralera lati awon igba iwaju itanakole: latowo awon Gallaeci ati awon Lusitanians, o bo si inu Ileobaluaye Romu be sini awon eniyan elede Jemani bi Suevi ati awon Visigoths na tedo sibe, ni orundun 8k awon Mauri bori ibe. Nigba Reconquista awon Elesin Kristi, Portugal seda ara re bi ileoba alominira, tori ni won se unpe bi orile-ede-ajoba togbojulo ni Europe.[9]

Ni orudnun 15k ati 16k, ntoripe o lewaju Igba Iwari, Portugal di ileobaluaye to nile kakiri Afrika, Asia, Oseania, ati Gusu Amerika, lati di ikan ninu awon alagbara itokowo, oloselu ati ologun lagbaye. Ileobaluaye Portugal ni ileobaluaye akariaye akoko ninu itan,[10] ati eyi to pejulo ninu gbogbo awon obaluaye alamusin Europe. Sibesibe, ipo orile-ede ti je riresile gan titi to fi di orundun 19k, agaga leyin ilominira ile Brasil, to je imusin totobijulo re.



Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Cite error: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named ine.pt
  2. Pordata, "Base de Dados Portugal Contemporâneo". Accessed on March 7, 2011.
  3. http://www.ine.pt/scripts/flex_v10/Main.html
  4. 4.0 4.1 4.2 4.3 "Portugal". International Monetary Fund. http://www.imf.org/external/pubs/ft/weo/2011/01/weodata/weorept.aspx?sy=2008&ey=2011&scsm=1&ssd=1&sort=country&ds=.&br=1&c=182&s=NGDPD%2CNGDPDPC%2CPPPGDP%2CPPPPC%2CLP&grp=0&a=&pr.x=40&pr.y=5. Retrieved 6 May 2011. 
  5. "Gini Index". World Bank. http://data.worldbank.org/indicator/SI.POV.GINI/. Retrieved 2 March 2011. 
  6. "Human Development Report 2010". United Nations. 2010. http://hdr.undp.org/en/media/HDR_2010_EN_Table1.pdf. Retrieved 5 November 2010. 
  7. The Euromosaic study, Mirandese in PortugalÀdàkọ:Dead link, europa.eu – European Commission website. Retrieved January 2007.
  8. (Potogí) Portal do GovernoÀdàkọ:Dead link
  9. Brian Jenkins, Spyros A. Sofos, "Nation and identity in contemporary Europe", p.145 Routledge, 1996, ISBN 0-415-12313-5
  10. Melvin Eugene Page, Penny M. Sonnenburg, p. 481

Àdàkọ:Link FA

Àdàkọ:Link FA Àdàkọ:Link FA Àdàkọ:Link FA Àdàkọ:Link FA