Bhùtán

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Ilẹ̀ọba ilẹ̀ Bhùtán
Kingdom of Bhutan
འབྲུག་ཡུལ་

Brug rGyal-Khab (Wylie)
Dru Gäkhap
Àsìá
Orin-ìyìn orílẹ̀-èdèDruk Tsendhen
Olúìlú Thimphu
Èdè oníbiṣẹ́ Dzongkha
Orúkọ aráàlú Ará Bhutan
Ìjọba Constitutional democratic monarchy
 -  King Jigme Khesar Namgyel Wangchuck
 -  Prime Minister Jigme Y. Thinley
Formation Early 17th century 
 -  Wangchuk Dynasty 17 December 1907 
 -  Constitutional Monarchy 2007 
Ààlà
 -  Àpapọ̀ iye ààlà 38,394 km2 
14,824 sq mi 
 -  Omi (%) <1 (estimate)
Alábùgbé
 -  Ìdíye July 2009 691,141[1] (163rd)
 -  2005 census 634,982[2] 
 -  Ìṣúpọ̀ olùgbé 18.1/km2 (154th)
47/sq mi
GIO (PPP) ìdíye 2009
 -  Iye lápapọ̀ $3.518 billion[3] 
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $5,212[3] 
GIO (onípípè) Ìdíye 2009
 -  Àpapọ̀ iye $1.269 billion[3] 
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $1,880[3] 
HDI (2007) 0.619[4] (medium) (132nd)
Owóníná Ngultrum2 (BTN)
Àkókò ilẹ̀àmùrè BTT (UTC+6:00)
 -  Summer (DST) not observed (UTC+6:00)
Ìwakọ̀ ní ọwọ́ left
Àmìọ̀rọ̀ Internet .bt
Àmìọ̀rọ̀o tẹlifóònù 975
1 The population of Bhutan had been estimated based on the reported figure of about 1 million in the 1970s when the country had joined the United Nations and precise statistics were lacking.[5] Thus using the annual increase rate of 2–3%, the most population estimates were around 2 million in the year 2000. A national census was carried out in 2005 and it turned out that the population was 672,425. Consequently, United Nations Population Division had down-estimated the country's population in the 2006 revision[6] for the whole period from 1950 to 2050.
2 Indian rupee is also legal tender

Àwọn Akóìjánupọ̀: 27°25′01″N 90°26′06″E / 27.417°N 90.435°E / 27.417; 90.435 Ileoba ile Bhutan (pípè /buːˈtɑːn/) je orile-ede tileyika ni Guusu Asia, to budo si apailaorun eti awon Oke Himalaya o si ni bode ni guusu, ilaorun ati iwoorun pelu orile-ede Olominira ile India ati ni ariwa pelu Tibet. Awon ara Bhutan n pe orile-ede won ni Druk Yul (Dzongkha: འབྲུག་ཡུལ་ 'drug yul) to tumo si "Ile Dragon" ni ede Tibet.[7] Awon ara Bhutan je eya eniyan Tibet. Bakanna wo tun ni esin ati asa pelu awon ara Tibet.



Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àdàkọ:Link FA