Dag Hammarskjöld

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Dag Hammarskjöld
2nd Secretary-General of the United Nations
Lórí àga
10 April 1953 – 18 September 1961
Asíwájú Trygve Lie
Arọ́pò U Thant
Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́
Ìbí 29 Oṣù Keje, 1905(1905-07-29)
Jönköping, Sweden
Aláìsí 18 Oṣù Kẹ̀sán, 1961 (ọmọ ọdún 56)
Ndola, Federation of Rhodesia and Nyasaland
Ọmọorílẹ̀-èdè Swedish
Ẹ̀sìn Lutheran/Church of Sweden

Dag Hjalmar Agne Carl Hammarskjöld (sv-Dag_Hammarskjöld.ogg Dag Hammarskjöld ) (29 July 1905 – 18 September 1961) je diplomati, onimo oro-okowo ati oludako ara Swidin. O je Akowe Agba keji Aparapo awon Orile-ede lati April 1953 titi di ojo to se alaisi ninu ijamba baalu ni September 1961. Ohun nikan ni o gba Ebun Alafia Nobel leyin to se alaisi.[1] Bakanna Hammarskjöld nikan na tun ni Akowe Agba U.N. to se alaisi lenu ise.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]


Àdàkọ:Link FA