Kòréà Gúúsù

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Republic of Korea
대한민국
大韓民國
Daehanmin(-)guk
Àsìá
MottoBenefit all mankind (홍익인간)
(Unofficial motto)
Orin-ìyìn orílẹ̀-èdè
Fáìlì:Aegukga instrumental.ogg

Aegukga (애국가) The Patriotic Song
Olúìlú
(àti ìlú títóbijùlọ)
Seoul
37°35′N 127°0′E / 37.583°N 127°E / 37.583; 127
Èdè oníbiṣẹ́ Korean
Official scripts Hangul
Orúkọ aráàlú Ará South Korea
Ìjọba Presidential republic
 -  President Park Geun-hye
 -  Prime Minister Jung Hong-won
Aṣòfin National Assembly
Establishment
 -  National Foundation Day October 3, 2333 BCE 
 -  Independence declared March 1, 1919 
 -  Provisional Government April 13, 1919 
 -  Liberation August 15, 1945 
 -  Constitution July 17, 1948 
 -  Government proclaimed August 15, 1948 
Ààlà
 -  Àpapọ̀ iye ààlà 100,210 km2 (108th)
38,691 sq mi 
 -  Omi (%) 0.3
Alábùgbé
 -  Ìdíye 2010 48,875,000[1] (24th)
 -  Ìṣúpọ̀ olùgbé 491/km2 (21st)
1,271/sq mi
GIO (PPP) ìdíye 2010
 -  Iye lápapọ̀ $1.457 trillion[2] 
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $29,790[2] 
GIO (onípípè) Ìdíye 2010
 -  Àpapọ̀ iye $986.256 billion[2] 
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $20,165[2] 
Gini (2007) 31.3[3] (low
HDI (2010) 0.877[4] (very high) (12th)
Owóníná South Korean won (₩) (KRW)
Àkókò ilẹ̀àmùrè Korea Standard Time (UTC+9)
 -  Summer (DST) not observed (UTC+9)
Ìdá ọjọ́ọdún yyyy년 mm월 dd일
yyyy/mm/dd (CE)
Ìwakọ̀ ní ọwọ́ right
Àmìọ̀rọ̀ Internet .kr
Àmìọ̀rọ̀o tẹlifóònù 82
1 Mobile phone system CDMA, WCDMA, HSDPA and WiBro
2 Domestic power supply 220V/60 Hz, CEE 7/7 sockets

Kòréà Gúúsù, fun onibise gege bi Orile-ede Olominira ile Korea (ROK) (Àdàkọ:Lang-ko, pípè [tɛːhanminɡuk̚]  ( listen)), je orile-ede ni Ilaorun Asia, to budo si ilaji apaguusu Korean Peninsula. O ni bode mo Saina ni iwoorun, Japan ni ilaorun, ati Ariwa Korea ni ariwa. Oluilu re ni Seoul. Guusu Korea dubule si agbegbe ojuojo lilowooro pelu awon oke. Agbegbe bo itobi to je 100,032 ilopo awon kilomita mole, o si ni iye eniyan to ju egbegberun 50 lo.[5]



Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]