Bósníà àti Hẹrjẹgòfínà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Bósníà àti Hẹrjẹgòfínà
Bosnia and Herzegovina
Bosna i Hercegovina
Босна и Херцеговина
Àsìá Àmì ọ̀pá àṣẹ
Orin-ìyìn orílẹ̀-èdèDržavna himna Bosne i Hercegovine
The National Anthem of Bosnia and Herzegovina
Ibùdó ilẹ̀  Bósníà àti Hẹrjẹgòfínà  (green)on the European continent  (dark grey)  —  [Legend]
Ibùdó ilẹ̀  Bósníà àti Hẹrjẹgòfínà  (green)

on the European continent  (dark grey)  —  [Legend]

Olúìlú
(àti ìlú títóbijùlọ)
Coat of arms of Sarajevo.svg Sarajevo
43°52′N 18°25′E / 43.867°N 18.417°E / 43.867; 18.417
Èdè oníbiṣẹ́ Bosnian/Croatian/Serbian[1]
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn  48% Bosniak
37% Serb
14% Croat[2]
Orúkọ aráàlú Ará Bósníà àti Hẹrjẹgòfínà
Ìjọba Parliamentary republic[3]
 -  High Representative Valentin Inzko1
 -  Presidency members Haris Silajdžić2
Nebojša Radmanović3
Željko Komšić4
 -  Prime Minister Nikola Špirić
Independence
 -  Formed August 29, 1189 
 -  Banate established 1154 
 -  Independence lost
   to Ottoman Empire conquest
1527 
 -  Annexation of Bosnia by Austro-Hungarian Empire 1908 
 -  National Day November 25, 1943 (establishing of the anti-fascist governing organ ZAVNOBIH
 -  Independence Day (from the SFR Yugoslavia) March 1, 1992 
 -  Observed April 6, 1992 
Ààlà
 -  Àpapọ̀ iye ààlà 51,129 km2 (127th)
19,767 sq mi 
Alábùgbé
 -  Ìdíye 2009 4,613,414[2] (120th5)
 -  1991 census 4,377,053 
 -  Ìṣúpọ̀ olùgbé 90,2/km2 (126th5)
230/sq mi
GIO (PPP) ìdíye 2009
 -  Iye lápapọ̀ $29.477 billion[4] 
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $7,361[4] 
GIO (onípípè) Ìdíye 2009
 -  Àpapọ̀ iye $17.133 billion[4] 
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $4,278[4] 
Gini (2007) 30.15 (low
HDI (2008) 0.812 (high) (76th)
Owóníná Convertible Mark (BAM)
Àkókò ilẹ̀àmùrè CET (UTC+1)
 -  Summer (DST) CEST (UTC+2)
Ìwakọ̀ ní ọwọ́ right
Àmìọ̀rọ̀ Internet .ba
Àmìọ̀rọ̀o tẹlifóònù 387
1 Not a government member; the High Representative is an international civilian peace implementation overseer with authority to dismiss elected and non-elected officials and enact legislation
2 Current presidency Chair; Bosniak.
3 Current presidency member; Serb.
4 Current presidency member; Croat.
5 Rank based on 2007 UN estimate of de facto population.
Map Bih entities.png

Bósníà àti Hẹrjẹgòfínà (pípè /ˈbɒzni.ə (ænd) hɜrtsɨˈɡoʊvɨnə/ (Speaker Icon.svg listen)[5] or /ˌhɜrtsɨɡoʊˈviːnə/;[6] Bosnian, Croatian, Serbian Latin: Bosna i Hercegovina; Bosnian and Serbian Cyrillic: Босна и Херцеговина) je orile-ede ni Guu-Apailaorun Europe, ni Peninsula Balkani. O ni bode mo Kroatia ni ariwa, iwoorun ati guusu, Serbia ni ilaorun, ati Montenegro si guusuilaorun, Bosnia ati Herzegovina (bakanna: Bosnia-Herzegovina/Bosnia ati Hercegovina) je ku di ko je ayikanule, ayafi fun 26 kilometres (16 miles)Àdàkọ:Convert/test/Anone ebado Omi-okun Adriatiki, ni ilu Neum.[7][8] Abenu orile-ede na je kiki okegiga ni arin ati si guusu, ilegiga ni ariwaiwoorun, ati ile pelebe ni ariwa ilaorun. Ninu na tu ni ibi jeografi totobiju to ni ojuojo orile iloworo, to ni igba orun gbigbona ati igba otutu to ni yinyin. Eti apaguusu re ni ojuojo Mediteraneani ati ojuile pelebe.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. There is a single official language of Bosnia and Herzegovina, which goes under three names. From the (1993) language law:
    In the Republic of Bosnia and Herzegovina, the Ijekavian standard literary language of the three constitutive nations is officially used, designated by one of the three terms: Bosnian, Serbian, Croatian. Both alphabets, Latin and Cyrillic, are equal.
    (Language in the former Yugoslav lands (2004) Ranko Bugarski, Celia Hawkesworth. p 142)
  2. 2.0 2.1 Bosnia and HerzegovinaCIA World Factbook
  3. https://www.cia.gov/library/publications/the-world-factbook/geos/bk.html
  4. 4.0 4.1 4.2 4.3 "Bosnia and Herzegovina". International Monetary Fund. http://www.imf.org/external/pubs/ft/weo/2010/01/weodata/weorept.aspx?sy=2007&ey=2010&scsm=1&ssd=1&sort=country&ds=.&br=1&c=963&s=NGDPD%2CNGDPDPC%2CPPPGDP%2CPPPPC%2CLP&grp=0&a=&pr.x=56&pr.y=12. Retrieved 2010-04-21. 
  5. Àdàkọ:USdict
  6. "Bosnia and Herzegovina – Definition of Bosnia and Herzegovina at". Yourdictionary.com. http://www.yourdictionary.com/bosnia-and-herzegovina. Retrieved 2010-01-25. 
  7. Field Listing – Coastline, The World Factbook, 2006-08-22
  8. Bosnia and Herzegovina: I: Introduction, Encarta, 2006. Archived 2009-10-31.

Àdàkọ:Link FA