Azerbaijan
Azerbaijan Ní ètò ìkànìyàn 1995, àwon tí ó ń so èdè yìí jé mílíònù méjè àbò. Òun ni ó jé èdè ìjoba fún Azerbaijani níbi tí àwon ìdá méta nínú mérin àwon tí ó ń gbé ibè ti ń so ó. Àwon ìdá méfà nínú ogórùn-ún àwon ènìyàn tí ó ń gbé Rósía ni ó ń so èdè yìí. Àwon èdè bú méjìlà mìíràn tún wà èyí tí Avar àti Armerican wà lára won.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
- ↑ The International Population Day, The demographic situation in Azerbaijan, The State Statistical Committee of the Republic of Azerbaijan, 11 July 2011
- ↑ 2.0 2.1 2.2 2.3 "Azerbaijan:Report for Selected Countries and Subjects". International Monetary Fund. http://www.imf.org/external/pubs/ft/weo/2011/01/weodata/weorept.aspx?sy=2008&ey=2011&scsm=1&ssd=1&sort=country&ds=.&br=1&c=912&s=NGDPD%2CNGDPDPC%2CPPPGDP%2CPPPPC%2CLP&grp=0&a=&pr.x=45&pr.y=0. Retrieved April 12, 2011.
|
|