Àndórà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Principality of Andorra
Ilẹ̀-Ọmọba Andorra
Principat d'Andorra
Àsìá
Motto"Virtus Unita Fortior"  (Latin)
"Strength United is Stronger"
Orin-ìyìn orílẹ̀-èdèEl Gran Carlemany, Mon Pare  (Catalan)
The Great Charlemagne, my Father

Ibùdó ilẹ̀  Àndórà  (circled in inset)on the European continent  (white)  —  [Legend]
Ibùdó ilẹ̀  Àndórà  (circled in inset)

on the European continent  (white)  —  [Legend]

Olúìlú
(àti ìlú títóbijùlọ)
Andorra la Vella
42°30′N 1°31′E / 42.5°N 1.517°E / 42.5; 1.517
Èdè oníbiṣẹ́ Catalan
Orúkọ aráàlú Ará Andorra
Ìjọba Parliamentary democracy and Co-principality
 -  French Co-Prince François Hollande
 -  Episcopal Co-Prince Joan Enric Vives Sicília
 -  Head of Government Antoni Martí
Independence
 -  Paréage 1278 
Ààlà
 -  Àpapọ̀ iye ààlà 468 km2 (196th)
181 sq mi 
 -  Omi (%) 0
Alábùgbé
 -  Ìdíye 2007 71,822 (194th)
 -  2006 census 69,150 
 -  Ìṣúpọ̀ olùgbé 154/km2 (69th)
393/sq mi
GIO (PPP) ìdíye 2005
 -  Iye lápapọ̀ $2.77 billion (177th)
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $38,800 (unranked)
Owóníná Euro (€)1 (EUR)
Àkókò ilẹ̀àmùrè CET (UTC+1)
 -  Summer (DST) CEST (UTC+2)
Àmìọ̀rọ̀ Internet .ad2
Àmìọ̀rọ̀o tẹlifóònù 376
1 Before 1999, the French franc and Spanish peseta. Small amounts of Andorran diners (divided into 100 centim) were minted after 1982.
2 Also .cat, shared with Catalan-speaking territories.

Àndórà tabi fun iseoba o je Ilẹ̀-Ọmọba Andorra, bakanna won tun mo si Ilẹ̀-Ọmọba àwọn Àfonífojì ilẹ̀ Andorra[1] (Principality of the Valleys of Andorra) je orílẹ̀-èdè aláfilẹ̀yíká ni apa guusuiwoorun Europe.

Nínú ètò ìkànìyàn 1995, àwon tí ó ń gbé Andorra jé egbèrún méjì-dún-láàádorin (68,000). Àwon èdè tí ó jé ti ìjoba níbè ni Kàtáláànù tí ìpín ogóta nínú ogórùn-ún ń so (60%) àti èdè faransé. Wón tún ń so Kàsìtílíànù ti àwon Pànyán-àn-àn gan-an fún òwò àgbáyé àti láti fi bá àwon tí ó bá wá ye ìlú won wo sòrò .


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Funk and Wagnalls Encyclopedia, 1991